Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà—Ta Ni Wọ́n? Kí Ni Wọ́n Gbà Gbọ́?
Ìfẹ́ àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ni pé kó o mọ àwọn dáadáa.
Ọlọ́run
Kí Ni Ọlọ́run Ń Béèrè Lọ́wọ́ Wa?
Ǹjẹ́ gbogbo ẹ̀sìn ni inú Ọlọ́run dùn sí, tàbí ẹyọ kan ni? Báwo lo ṣe lè mọ àwọn Kristẹni tòótọ́?
- Àwọn Ìránṣẹ́ Ọlọrun Gbọ́dọ̀ Mọ́ Tónítóní
- Àwọn Àṣà Tí Ọlọrun Kórìíra
- Àwọn Èrò Ìgbàgbọ́ àti Àṣà Ìṣẹ̀dálẹ̀ Tí Inú Ọlọrun Kò Dùn Sí
- Fífọ̀wọ̀ Hàn fún Ìwàláàyè àti Ẹ̀jẹ̀
- Báwo Ni O Ṣe Lè Rí Ìsìn Tòótọ́?
- Bí A Ṣe Ṣètò Àwọn Ẹlẹ́rìí Jehofa
- Ríran Àwọn Ẹlòmíràn Lọ́wọ́ Láti Ṣe Ìfẹ́ Ọlọrun
- Ìpinnu Rẹ Láti Sin Ọlọrun
Ìkànnì orí Íńtánẹ́ẹ̀tì tẹ́ ẹ ti lè rí ìsọfúnni tó ṣeé gbára lé nípa ìgbàgbọ́, ẹ̀kọ́, àti ìgbòkègbodò àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà. Watchtower Bible and Tract Society of New York, Inc. ni àjọ tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń lò, èyí tá a fi orúkọ rẹ̀ sílẹ̀ lábẹ́ òfin.
Bá ò bá fi hàn pé ó yàtọ̀, inú Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun la ti mú gbogbo ẹsẹ Ìwé Mímọ́ tá a lò.
Ìkésíni Tá A Nawọ́ Rẹ̀ sí Ọ
Ṣé wàá fẹ́ ká wá máa ṣe ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì inú ilé pẹ̀lú rẹ kó o lè mú ìmọ́ rẹ pọ̀ sí nípa Bíbélì?
Ká Bíbélì lórí íńtánẹ́ẹ̀tì
Ìwé Mímọ́ ní Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Láìka irú ipò tó yí wa ká sí, Bíbélì ní àwọn ìtọ́ni àti ìmọ̀ràn tá a nílò. Máa kà á lójoojúmọ́
Ìwé Ìtàn Bíbélì
Ìwé ìtàn tòótọ́ ni ìwé yìí. Àwọn ìtàn tó wà nínú ìwé yìí wá láti inú Bíbélì tó jẹ́ ìwé tó ju gbogbo ìwé lọ láyé.
Ṣe Wàá Fẹ́ Mọ Òtítọ́?
Òtítọ́ nípa kí ni? Òtítọ́ nípa ìdáhùn sáwọn ìbéèrè tó ṣe pàtàkì jù lọ táwọn èèyàn títi béèrè rí.
Òpin Ìsìn Èké Sún Mọ́lé!
Kí ni ìsìn èké? Báwo ni òpin ṣe máa dé bá ìsìn èké? Kí ni wàá ṣe tí ò fi ní kàn ọ́?

